Gbogbo awon ololufe gbajumo oseretiata okunrin nni ,to tun sese S'egbeyawo iyen Lateef Adedimeji ni won ti n ki I ku oriire ti Ile nla to sese ko silu Eko.
Oko Adebimpe gbe aworan Ile alaranbara naa sori ikanni ayelujara re ,ti awon ololufe ati akeegbe re si ti n ki i ku oriire.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment