Ojo Monde ojo aje ose yii ni awon janduku wo Aafin Oba Agodo nitosi ijoba Ibile Ewekoro nipinle Ogun,ti won si dana sun Aafin oba Alade naa pelu oba Odetola fun ra e.Inu ibanuje ni gbogbo omo Bibi ilu Agodo wa bayii pelu isele kayeefi to sele ninu ilu naa.A gbo pe won sun Oba yii to si jona koja siso.
Oga Olopaa ipinle Ogun fidi isele yii mule to si so pe ise n lo lati wa awon amokunseka to da emi oba Odetola legbodo lairotele.

No comments:
Post a Comment