Tafa onitiata ku lojiji - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, February 1, 2022

Tafa onitiata ku lojiji

Ojo tuside to koja yii ni iroyin naa gba igboro pe okan ninu agba oje fiimu agbelewo iyen baba Tafa Oloyede ti jade laye.Ogbeni John Adewunmi eniti awon ti e n pe ni Tafa Oloyede la gbo pe o papoda lojo tuside.
Baba fi iyawo kan atawon omo saye lo.


No comments:

Post a Comment

Pages