Nitori ti won wo aso esu beleke,awon ololufe awon oseretiata meteeta yii n binu si won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, February 13, 2022

Nitori ti won wo aso esu beleke,awon ololufe awon oseretiata meteeta yii n binu si won

Mercy Aigbe,Damilola Oni ati Eniola Ajao le n wo ninu foto yii,Mercy iyawo osingin tuntun lo gbe aworan naa sori ero ayelujara re to si ko o sibe pe 'awon omoge ijimere'loju ese ni awon ololufe fiimu Yoruba ti bere si I ni bu won paapaa Damilola to ko gbogbo omu sita.Kini eyin ri si foto naa?


No comments:

Post a Comment

Pages