Nigba ti Akobi Esan to je omo Bibi ilu Badagry n ba wa soro lo ti so pe Ankara lawon eeyan yoo fi wole lojo naa,Alaaji Saoty Arewa ni yoo dalubole .Awon eeyan Pataki ti yoo wa nikale lojo naa ni Alaaji Ganiy Akewusola lati idiroko ati Alaaji Rasak Adeleke Agbawo pelu awon eeyan jankan jankan miiran, Akobi Esan wa n dupe lowo Alaaji Essy Ismail atiyawo re fun aduroti won.Ekunrere iroyin n bo nipa ayeye naa laipe.


No comments:
Post a Comment