
Iroyin naa gba igboro pe Alaaja Alaragbo ti papoda leyin aisan ranpe,okan ninu olorin Waka to n se daadaa ni oloogbe Alaragbo,Koda o sese de gbe Orin tuntun kan jade laipe yii ni ki iku to yo owo e l'awo.Won ti sinku omo Bibi ipinle Ogun naa nilana musulumi,adura wa ni pe ki Olorun te mama naa si Afefe ire.


No comments:
Post a Comment