
Osuba sadankata ni awon to ri ohun ti Olori fun gbogbo awon onimoto ilu Eko iyen Alaaji Musiliu Ayinde Oluomo h laarin iyabo Ojo ati Fathia Balogun ni won ti n ki I ,pelu bo se pari ija olojo pipe aarin awon oseretiata naa,a tun gbo pe oluulu gege bii oruko re tun ti pari ija to wa laarin Olori ebi Oganla iyen Alaaji Wasiu Alabi ati Alaaji Ahmad Alawiye


No comments:
Post a Comment