O mase o!Arewa obinrin ku sinu ijamba oko , ayeye igbeyawo re si ku osu kan. - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Thursday, January 6, 2022

O mase o!Arewa obinrin ku sinu ijamba oko , ayeye igbeyawo re si ku osu kan.

Ojo karun osu keji yii gan an lo ye ki arewa obinrin te n so aworan re yii yoo se igbeyawo sugbon ti elemii ti gba a ,inu ijamba oko lojuna Gadau nipinle Bauchi ni ijamba oko naa ti waye,lesekese la gbo pe emi arewa naa ba isele yii lo.


No comments:

Post a Comment

Pages