A gbo pe Ogbeni Eluyera so pe ki afesona re to je eni odun mejidinlogbon lo se oyun inu re sugbon nitori iyen ko jale lo mu u pinnu ati pa a.
Sa o,owo awon olopaa ipinle Ogun ti te won ,ti alukoro olopaa ipinle naa iyen Asp Abimbola si fidi isele naa mule.


No comments:
Post a Comment