
Ti eyin ba n wa ileese gidi to le mu yin lo si Meka,Umurrah laisi wahala tabi idaamu,ileese Alhatyk travel and tours nikan lo le fun yin no ohun gbogbo ti e n wa.Alaaji Badmus to je alase ati oludari ileese Alhatyk ti olu ileese won wa ni Amje nitosi Alagbado nilu Eko ti so pe irorun ni lilo Umurrah ati Hajj ba de nileese awon bee ni e o ni kabamo ti e ba ba won dowo po.


No comments:
Post a Comment