Gbogbo ojo kerinla osu keta ni ojo ibi re,Adedoyin Owolabi Aya Ademola,mama Niniola,iya to bi Richard,ma jo sibi to wun e jare,Ori elegan lo daru.
Adura wa ni pe emi e a sopo odun laye ninu owo ati alaafia,gbogbo wa nileese iroyin tojubole lo nki e pe api Baide tuu yuuuu.

No comments:
Post a Comment