Alase ati oludari ileese Mainframe ni Ogbeni Tk gege bii inagije Tunde Kelani,Alimo so pe pelu aduru owo ti Tk ri nidi fiimu Ayinla Omowura, milioonu kan pere ni Tk fawon molebi to si je pe owo to le ni ogorin milioonu ni Tk ri lori fiimu naa.
Alimo tun salaye fun 'Tojubole pe awon molebi ro pe oun ti gba owo goboi lowo Tk ni pelu iha baba si omo ti oun ati Tk ko si ara .
O so pe oun finu wenu lo mu oun maa towo bo iwe adehun pelu Tk sugbon ti Tk fagba han oun nipa ireje.


No comments:
Post a Comment