Inu ibanuje ni okan lara awon oseretiata obinrin nni iyen Kemi Afolabi wa bayii pelu bi awon Dokita re se ti so pe odun marun-un lo ku fun un lori oke eepe,ti arewa obinrin naa si ti lo odun kan ninu odun Marun un.
Aisan 'Lupus la gbo pe o n se Kemi to si je pe owo to le ni milioonu kan lo maa n nfi toju Ara e losoosu,adura wa ni pe ki Olorun lora emi Kemi fun wa (Amin)

No comments:
Post a Comment