Abiodun Amole Okin eniti gbogbo awon ololufe e mo si Capo Money tun ti sekojade Orin tuntun to pe akole re ni 'my destiny'.Odun 2009 ni omo Bibi ilu Ibadan yii bere ise Orin Fuji,to si ti se awo Orin merin otooto.
Alaaji Abass Akande Obesere ni Capo pe ni awokose re nidi ise Orin Fuji,ni bayii Capo ti wa so pe ki awon ololufe oun ba oun ra awo Orin oun tuntun naa ti ileese Sarolaj ba oun ta.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment