Temilola lo puroduusi fiimu naa nigbati Ojopagogo je adari iyen dairekito.A gbo pe odo iyaafin Rose Odika ni Temilola to je omo Bibi ipinle Osun ti kose fiimu Koda obinrin naa lo ba a dari fiimu re to pe akole re ni 9th of September ti yoo jade laipe.
Ju gbogbo e lo,fiimu Akanke Oba ti jade sori Telifisan YORUBAHOOD ti apa kinni ati apa keji si ti n mi igboro titi bayii,awon agba osere to kopa ninu fiimu naa ni ,baba Aderupoko,Ogbeni Ojopagogo,Moji Afolayan,Femi Adebayo, Temilola Akinwunmi atawon mi-in.


No comments:
Post a Comment