Aisan ropa-rose ti mu olorin Fuji yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, April 3, 2022

Aisan ropa-rose ti mu olorin Fuji yii

Ode ariya kan ni Alaaji Iyanda Sawaba wa,ti a gbo pe nise lo Deedee subu, opelope awon eeyan ti won sare gbe e lo si Ile iwosan UCH nibadan.A gbo pe Alaaji Sawaba ko le soro mo,ero ti eeyan fi n mi(oxygen) ni ogbontarigi olorin Fuji naa fi n mi bayii.


No comments:

Post a Comment

Pages