Gbogbo ojo kefa osu kerin ni ayajo ojo ibi Alaaji Ajibade Akewusola Adekunle Iyanda eniti gbogbo eeyan mo si Olorun nidahun adura,ohun to tun wa je ki ojo naa tun yato ni bo se je pe ojo yii Kanna ni akobi Alaaji naa tun n s'ojo ibi,Alaaji Abosede Akorede Sofiat naa le odun kan Lori oke eepe.
Awon ore,Ara atojulumo ni won n ba baba at'omo dupe lowo Olorun fun idasi emi won,awa naa wa n ki won pe 'Api Baide tuuuu yuuuu Dadi ati DotA re.

No comments:
Post a Comment