O salaye pe oun ko ri idunnu ninu igbeyawo naa pelu bii oko oun ki n se fi Ife han si oun bee lo tun je pe ki i ba oun gbe bukata kankan,pelu bo se je oun lo ja ibale oun sibe ko fi Ife han to si oun.
Yewande so pe Ogbeni naa tun maa n ko obinrin,idi eyi ni oun se ko o sile,o salaye pe Abiodun lo Koko ko kuro ninu Ile ti awon mejeeji Jo n gbe,sa o,oun naa ti gba fun Olorun lati ko o sile.


No comments:
Post a Comment