Minisita fun ilera ti so pe ohun gidi ni ifetosomo bibi - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, April 13, 2022

Minisita fun ilera ti so pe ohun gidi ni ifetosomo bibi

Ose to koja ni minisita fun eto ilera lorile ede yii ti so pe ohun to dara ni lati maa feto somo Bibi,Dokita Osagie Ehanire so pe,oun nife si lati mo oniruuru isoro ti awon obinrin n koju,awon ohun elo to wa nile iwosan kaakiri ipinle merindinlogoji to wa Lorile ede yii.
Ibi ipade olojo meji to waye nipinle Kwara ni minisita ti soro yii latenu asoju re iyen Dokita Samuel Oyeniyi,o salaye pe ajo ilera lorile ede yii nife lati mo awon idojuko ti Ile iwosan kookan n koju pelu ileri pe awon setan lati wa ojutu si i.



No comments:

Post a Comment

Pages