Ipinle Kwara ni eto naa ti waye lose die seyin nibi ti Dokita Samuel Oyeniyi ti soju minisita fun eto ilera iyen Dokita Osagie Ehanire,ti asoju minisita si ti so pe emi awon araalu je iyebiye ,bee lo so pe Dokita Osagie nife lati mo isoro ti awon obinrin n koju,iye ohun elo itoju to wa lawon Ile iwosan kaakiri ipinle merindinlogoji to wa Lorile ede yii,bee lo so pe Inu minisita fun eto ilera yoo dun tawon obinrin ba le maa feto somo Bibi pelu.
Ipade olojo meji yii ti egbe Rotary naa se agbateru e ni minisita ti seleri lati pese awon ohun ti awon Ile iwosan kereje ati nla niilo.

No comments:
Post a Comment