Osupa figbeta pe Barryshowkey ko ba oun gba ode ere lamerika, B'oro se je ree jare-- Barryshowkey - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, April 15, 2022

Osupa figbeta pe Barryshowkey ko ba oun gba ode ere lamerika, B'oro se je ree jare-- Barryshowkey

Ose to koja ni oba Orin Iyen Alaaji Saheed Osupa so fun awon kan pe Inu oun ko dun pelu bi i omo oloogbe Barrister iyen Akanji Adewale Barryshowkey ko se ba oun gba ode ere,dipo ko sugba oun,Aare Akanni Shina ni Barryshowkey n pon seyin kiri.
Lati fidi ooto mule lo mu tojubole pe nomba Aare Shina ti ogolorinwa si je ko di mimo pe aheso Oro lasan ni Osupa n so,nitori Barryshowkey ko ba oun gba ode ere kankan.O salaye fun wa pe oun ti se akosile gbogbo ode ere ti oun yoo lo ki oun to kuro lorile ede yii.
Tojubole tun pe Barryshowkey ti oun naa si so pe Aare ko ko iyan oun kere nigba to bale sorile ede America eyi lo mu oun naa satileyin fun un ,o so pe Oba Orin de sodo awon tie ,Akanni naa si de sodo awon tie,ti oun si je okan lara awon ti Akanni.
O so pe oun ko pon Aare seyin rara sugbon kaluku lo mo eeyan e.Gbogbo Akitiyan wa lati ba Osupa soro lo jasi pabo nitori ko fi esi ranse titi ti a fi sakojopo iroyin yii tan.
Ju gbogbo e lo, Barryshowkey ti so pe awawi lasan ni ejo wewe ti Osupa n ro kiri pe oun ba Aare Akanni gba ere lorile ede America.


No comments:

Post a Comment

Pages