O sele!Won ni Emmanuella fo Wasiu Ayinde l'eti.Iro ni B'oro se je niyii--Agbenuso Wasiu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, April 15, 2022

O sele!Won ni Emmanuella fo Wasiu Ayinde l'eti.Iro ni B'oro se je niyii--Agbenuso Wasiu

A fi bi iroyin naa se gba igboro pe iyawo tuntun l'oode Mayegun Ile Yoruba iyen Alaaji Wasiu Ayinde ko igbaju igbamu fun un nigba to ka Oluaye mo ibi to ti n yinbo idi fun amugbalegbe re to je obinrin.
Sugbon ti Ogbeni Kunle Rasheed to je agbenuso Wasiu nidi ise iroyin so pe iro ni ati pe iroyin eleje ni iroyin naa nitori 'Okin'gege bii oruko inagije Emmanuella ko Raye pelu bo se gbajumo ojuse re gege bii iyawo ninu Ile Wasiu.


No comments:

Post a Comment

Pages