Nitori to ta Orin olorin fawon ileese ibanisoro,Tope Alabi olorin emi ha - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, April 18, 2022

Nitori to ta Orin olorin fawon ileese ibanisoro,Tope Alabi olorin emi ha

Gege bi iroyin to te wa lowo pe ,Tope Alabi to je okan lara gbajumo olorin kristeni se so pe nise ni obinrin naa lo ta Orin meta otooto to je ti Alaaji Tajudeen Bioku fun ileese elero ibanisoro.Ileese glo,mtn ati Airtel ni Tope ta orin'Jesu Olurapada, E gbe e ga ati 'Angeli mi fun iyen leyin to ti towo bo iwe adehun pelu Alaaji Bioku to je oludari ileese NPC record Lorile ede America.
Odun 2006 ni Tope ati Alaaji naa towo bo iwe ti ileese NPC si ti sanwo ti Tope beere fun o tumo si pe Tope ko ni ase lori Orin naa mo,sugbon ti asiri pada tu sowo Alaaji naa ni odun 2011 pe o ti ta awon Orin yii fawon ileese ibanisoro naa.
Ejo ti wa ni kootu giga to wa ni Ikoyi bayii,Alaaji naa lo pe awon ileese ibanisoro lejo .


No comments:

Post a Comment

Pages