Loya Alaaji naa iyen Ogbeni Oyeniyi so pe awon ileese yii ko ni ase rara lati maa lo awon Orin meta naa iyen Angeli mi, E gbe e ga ati Jesu Olurapada nitori Tope se Orin naa fun Alaaji ni ti Alaaji so sanwo fun un nigba naa,Koda Tope towo bo iwe adehun ti awon iwe naa si wa pelu loya.
Alaaji Tajudeen Bioku to je oludari ileese NPC record to wa ni Orile ede America ti pe ileese ero ibanisoro glo, mtn ati Airtel lejo latari esun pe won n lo Orin oun ti Tope Alabi se fun oun laigba ase lowo oun.
No comments:
Post a Comment