Tosyno fe sayeye nla nilu Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, June 7, 2022

Tosyno fe sayeye nla nilu Eko

Odu ni Ogbeni Tosin eniti gbogbo eeyan mo si Tosyno je ,omo Bibi ilu Ijebu igbo nipinle Ogun naa ki n se aimo fun oloko,ojo sannde ojo kokandinlogun osu kefa yii ni gbajumo sorosoro naa yoo sayeye onibeji nilu Eko,ikojade Ori re ti akole re n je 'igbedide to tayo' ati Fifi ami eye da awon eeyan Lola ti yoo waye ni Gbongan Classic Arena lagbegbe Kola nilu Eko.
Tosyno Oloriire ti fiwe pe awon eeyan jankanjankan bii Oloye Ambrose Olutayo Somide atawon miiran,awon olorin bii Mega 99, Atorise,Dare Melody ni yoo wa nibe,Ronke Osodi Oke ati Afiz Owo ni yoo dari eto lojo naa fun Ankara ti yin e pe,08038367774.


No comments:

Post a Comment

Pages