Iku Osmond Gbadebo ti da wahala sile laarin awon oseretiata - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, June 7, 2022

Iku Osmond Gbadebo ti da wahala sile laarin awon oseretiata

Loooto lo ti se die ti iku ti mu Oloogbe Osmond Gbadebo lo laarin awon oseretiata,sugbon ti Wunmi Toriola ti oun naa je oseretiata ti so pe awon akeegbe oloogbe ko sedaro re to rara.
O so pe pupo ninu won ko yoju sibi eto isinku re ti iwa yii si ku die kaato,sugbon o je ohun iyalenu pe ko si oseretiata kankan to fun Wunmi l'esi Oro to so naa.


No comments:

Post a Comment

Pages