
Gbogbo eyin oloju aanu ni Omooba Ademola Adelakun eniti gbogbo eeyan mo si Megastar ,to tun je gbajumo puromota ati purodusa n fe iranlowo yin.Aisan Ito suga lo n yo Ogbeni Ademola laamu ti won si ti ge ese re osi bayii,sugbon lati gba itoju pipe loke okun nitori aisan yii ti fe sakoba fun egungun eyin re(spinal cord) .Orile ede Germany lo ti fe lo gba ojulowo itoju sii pelu Oogun milionu.


No comments:
Post a Comment