Baba to je oludasile ijo Sebilunajat,iyen ojo to maa n saanu awon mekunnu nipa pipese onje,owo ati titoju awon alaisan beeni ijo yii tun maa n ran awon eeyan lo si Meka.Oniwaasi agbaye yii tun salaye fun wa pe ki n se ohun to dara ki awon omoleyin Anobi maa bu Ara won tabi S'oko Oro si Ara won paapaa Lori ero ayelujara.


No comments:
Post a Comment