Barimade tun korin fawon omo yii,ki n se awon ogo weere yii nikan ni Alaaja fun lebun o,oun ati ore re timotimo nidi ise tiata iyen Alaaja Sakirat Olaide Bakare naa tun lo fun awon mola to maa n toro baara lebun owo ati ounje pelu,bee lo korin fun won ti inu gbogbo won si dun lojo naa.
Gbogbo awon to ri ohun ti omo Oloogbe Barrister se yii ni won ti n gbe osuba sadankata fun-un nitori ko si olorin isilaamu to ti i se ohun ti omo Bibi ilu Ibadan naa se ri .Leyin eyi ni ayeye waasi waye pelu akole to so pe 'Ere to wa ninu fififunni fun eni to fifunni ati eni ti a fifun.


No comments:
Post a Comment