Purodusa awon olorin Fuji bii Saheed Osupa,Wasiu Ayinde,Alabi Pasuma atawon mi-in ni ,a gbo pe oba Orin to n se daadaa lorile ede America bayii iyen Alaaji Saheed Osupa ti fun Ogbeni yii lowo die to si tun seleri lati nawo iranlowo fun un siwaju si,sugbon to je pe won ti ri die ninu owo yii.
Sa o,owo to to milioonu meedogun ni won si nilo nitori kokoro bakiteria yii ti fe sakoba fun oju ati opa eyin okunrin naa.Ogbeni yii lo ko fiimu eyin oka, Babatunde Ishola Folorunsho atopo fiimu agbelewo mi-in.
No comments:
Post a Comment