Toyin ko Raye temi o--Kola Ajeyemi - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, July 1, 2022

Toyin ko Raye temi o--Kola Ajeyemi

Oko gbajumo oseretiata obinrin nni iyen Toyin Abraham Ajeyemi iyen Ogbeni Kola Ajeyemi to pariwo sita pe iyawo oun ko raye toun beeni ko setan lati maa tele oun atawon omo lo si soosi,ore re timotimo kan lo so asiri yii fun ti iyen de ti ba a gbe lo sodo awon oniroyin ayelujara.
Adura ti wa ni pe Ile alayo Toyin atoko re ko ni daru o sugbon ki Toyin naa gbiyanju lati fi aye sile fun idile re


No comments:

Post a Comment

Pages