Ara iya Ibeji omo araye le koya - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Friday, July 8, 2022

Ara iya Ibeji omo araye le koya

Odu ni iya Ibeji omo araye le laarin awon agba oje oseretiata obinrin,sugbon Ara Adenike gege bii oruko re ko ya bayii,Foluke Daramola lo je ko di mimo pe iya Ibeji niilo iranlowo awon eleyinju Aanu.Adura wa ni pe Olorun yoo fun iya Ibeji ni alaafia.


No comments:

Post a Comment

Pages