Orile ede Canada ni Libra iyen egbon Osupa fi sebugbe lati odun die seyin,ti Akorede Okunola iyen Alagbede Orin si wa ba se n ko iroyin yii Jo ,sugbon oun to wa je ki inu opo awon ololufe Orin Fuji n dun lasiko yii ni pe awon omo baba Kanna yii ti pari ija to wa laarin won,ti irepo si ti pada saarin awon mejeeji.
Opo awuyewuye lo n lo nigboro nigba kan nipa awon mejeeji yii sugbon ti Olori ebi Olufimo to pada dojuti awon ota e ti won ti n so kiri igboro pe aarin oun ati egbon e ko le gun rege mo.
Sa o,oba Orin to n se daadaa loke okun lasiko yii tun ti n gbero ati lo sorile ede Europe bayii,ti pupo ninu awon ololufe e si ti n sadura fun baba 'oni dollar bayii.


No comments:
Post a Comment