Aseyin ti Iseyin ti w'aja - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Sunday, July 24, 2022

Aseyin ti Iseyin ti w'aja

Aaro ojo sannde ni iroyin gba igboro pe Aseyin ti Iseyin iyen Oba Ganiy Adekunle Salawdeen ti pada lo ba awon baba nla re,eni odun mejilelogota ni kabiesi,to si wa lori ipo oba fun odun meedogun.


No comments:

Post a Comment

Pages