
Odu ni Wolii Faleyinmu je laarin awon iranse Olorun,baba naa ti wa so ohun ti iranse Olorun kankan ko so ri,Wolii ariran nni ti so pe,odu elawori ni odu ifa Jesu ati pe otura meji ni odu ifa Anobi Mohammed ,o salaye pe ifa ni Olorun Koko da beeni gbogbo Iran Yoruba je Iran ifa,pupo ninu awon iranse Olorun ni won wa lati idile onifa pelu.


No comments:
Post a Comment