Ariran agbaaye nni iyen Wolii Faleyinmu ti so jade pe,ki oseretiata obinrin iyen Funke Akindele ma daamu Ara e nitori ko le di igbakeji Gomina nipinle Eko rara,baba naa ti wa gba Funke nimoran pe to ba setan lati fe talaka nikan lo le mu u ni oko laye.
Wolii Faleyinmu tun so pe Oloye Tinubu ko le di Aare Orile ede yii ati pe gbolohun'O lu le ati 'emi lo kan ki n se gbolohun lasan,beeni Olorun ko fi han oun pe Oloye Tinubu ni yoo di Aare Orile ede yii.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment