O so pe ,o ye ki gbogbo eda mo pe ko si ohun kan ninu aye yii ju pe ki eda eeyan maa se daadaa lo,o tun salaye pe Oro yii ko yo awon adari wa Lorile ede yii sile,beeni ko yo awon Olori esin atawon borokini lawujo sile nitori pe ojuse wa ni lati maa toju awon alaini ati awon omo alailobi.
Oluso Genesis ti wa fi ehonu e han pelu awon ohun to n sele kaakiri Orile ede yii to si so pe o dara ki gbogbo awon oludasile ijo Kristi Koko ko awon omo ijo won leyin eyi ki won ko Orile ede pelu.
Pelu gbogbo enu ni omo Bibi ipinle Ogun yii fi so lojo naa pe,oun ko gbowo lowo oloselu kankan ri ,oun si setan lati dibo fun eni to wu oun ninu eto idibo to n bo lona.


No comments:
Post a Comment