A gbo pe nitori owo wa lowo Ogbeni Mulero ni won se Yan an,ti awon oba alade to wa ni agbegbe naa ko si ri ohunkohun se si I.
Ni bayii, Omooba Alexander Adegbemiro Idowu ti ke si ijoba Ipinle Ogun labe isakoso Ogbeni Dapo Abiodun lati da si Oro naa ki awon borokini to fi owo ola gba oun loju,bee lo dupe lowo Alake ti Ile Egba fun aduroti re.Sa o ,Oro naa si wa ni kootu ,ti ko si leto lati dade fun enikeni gege bii Aboro ilu Ibeshe sugbon ti Mulero ti gba Ade nigbati Oro si wa nile ejo.


No comments:
Post a Comment