
Odun kerin seyin ni arewa obinrin yii nijamba oko nilu Eko,o ti sise Abe lawon osibitu nla ni eemeji otooto nilu Eko sibe ese naa ko ti i le duro,ni bayii o niilo iranlowo lati lo sise Abe ni Orile ede Indian , milioonu meedogun ni omo Bibi ipinle Ogun naa n wa bayii,e le fi owo ranse si Akanti re,2406501671 Zenith Bank Omolola Ogunlaja,e le pe nomba re pelu,09160751408,e Seun.


No comments:
Post a Comment