Ikunle abiamo o!Won n wa awon odolangba merin ti won ri sinu odo igbalode Elegushi - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Thursday, August 18, 2022

Ikunle abiamo o!Won n wa awon odolangba merin ti won ri sinu odo igbalode Elegushi

Leyin ti won pari idanwo asekagba jade kuro ni kilaasi to gbeyin ni Girama,ileewe Girama Kuramo ni awon odo naa ti setan nilu Eko sugbon nibiti won ti lo se faaji ninu odo igbalode Elegushi ni Omi ti gbe merin lo ninu won.
Alamojuto odo igbalode naa iyen Alaaji Ayuba Elegushi fidi isele yii mule to si so pe Abass okan ninu awon omo ileewe naa lo ko won lo si apa ibikan nitosi odo yii iyen leyin tawon ti le won pada sugbon nitori Abass ti won si n wa oku ti e naa je okan ninu awon osise ibe lo je ko fagidi ko won lo Sapa ibomi in leyin tawon sekilo fun won.


No comments:

Post a Comment

Pages