Se loooto ni Doyin Kukoyi n fe Taiwo Hassan Ogogo? - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Thursday, August 18, 2022

Se loooto ni Doyin Kukoyi n fe Taiwo Hassan Ogogo?

Asiri ti pada tu pe,oko ere lawon oseretiata meejeji naa wa iyen Alaaja tuntun Doyin Kukoyi ati Alaaji Taiwo Hassan Ogogo wa sugbon ti opo awon ololufe won so pe o seese ko je awon mejeeji n fe Ara.
Omo Ogogo to n je Kira lo Koko tako Oro ti Doyin so pe,mo ti pade Ife mi,Ife tooto si wa' lesekese ni Kira omo Ogogo so pe,a o fe iyawo tuntun fun baba wa,Ile ti kun" ti Doyin si fun omo Ogogo l'esi pe,iya oko mi e tete ba wa mu deeti ojo igbeyawo e ma je ki Ile kun o.
Ju gbogbo e lo,asiri ti pada tu pe,oko ere fiimu agbelewo ti yoo mi igboro titi ni Doyin ati Ogogo wa ki n se pe won n fe Ara won rara.


No comments:

Post a Comment

Pages