O mase o,won pa arewa obinrin yii danu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Tuesday, August 16, 2022

O mase o,won pa arewa obinrin yii danu

Lojo tuside ose to koja ni won ji arewa obinrin te n wo foto e yii gbe,omo ileewe Poli ni Abeokuta ni,won ti pa a danu leyin ti a gbo pe won ko ibasun fun un.Olorun yoo maa so wa amin


No comments:

Post a Comment

Pages