Won n wa oko ayokele yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Friday, August 12, 2022

Won n wa oko ayokele yii

Enikeni to ba ba wa ri oko ayokele ti e n wo yii le pe nomba yii,08033586993 oko naa ni won ji gbe ni agbegbe Alakuko lose die seyin,Koda owo repete lo wa ninu e,oko to je ti Ogbeni Awolowo Olawale ati iyaafin Awolowo Omowunmi ti won n gbe ni ojule keje,Adugbo Kufile ni Alakuko nipinle Eko,awo olomi goolu ni oko naa ti nomba re je,FFA89AH(Kwara).


No comments:

Post a Comment

Pages