Ode Ariya ni won ti yinbon fun Ogbeni Oguntulu, amugbalegbe Alaga ijoba ibile Osodi - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, August 23, 2022

Ode Ariya ni won ti yinbon fun Ogbeni Oguntulu, amugbalegbe Alaga ijoba ibile Osodi

Ojo satide to koja nisele naa sele ni agbegbe Osodi nigba tawon igara olosa wo adugbo naa lasiko ti ayeye ariya n lo lowo ti won si pa Oguntulu to je amugbalegbe Alaga ijoba ibile Osodi

No comments:

Post a Comment

Pages