Afolabi pokunso nipinle Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, August 21, 2022

Afolabi pokunso nipinle Eko

Onisowo oko ayokele tita ni oloogbe Afolabi Ogunnaike sugbon a gbo pe ise naa ko lo deede,gbese po nile fun un idi eyi lo se pokunso.
Faamu Inu Ile e lo so okun mo to si pokunso iyen leyin to ko let's sile pe,ki awon ore oun mabinu soun.
O fi iyawo atomo kan saye lo.


No comments:

Post a Comment

Pages