Oko Mercy Aigbe n binu si i,nitori omu to ko sita nibi ayeye Oluaye fuji - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, August 20, 2022

Oko Mercy Aigbe n binu si i,nitori omu to ko sita nibi ayeye Oluaye fuji

Gbogbo awon to ri oju ti Alaaji Adeoti Kadim iyen oko arewa obinrin onitiata nni iyen Mercy Aigbe fi wo o lojo ayeye aadota odun ti Oluaye fawon onifuji iyen Alaaji Wasiu Ayinde ti n korin ni won ti n so pe Inu Ogbeni naa ko dun si iyawo re
Alaaji Adeoti to ti maa n so pe ko Dara ki obinrin maa si Ara sile gan niyawo e ko omu sita nibi ayeye Oluaye.


No comments:

Post a Comment

Pages