Oga onimoto Alaaji M.c Oluomo ta Ebun Oloyede l'ebun oko ayokele - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Thursday, August 11, 2022

Oga onimoto Alaaji M.c Oluomo ta Ebun Oloyede l'ebun oko ayokele

Inu idunnu ni agba oje oseretiata okunrin nni iyen Alaaji Ebun Oloyede eniti awon ololufe e mo si Olaiya Igwe wa bayii pelu bi Olori fun gbogbo awon onimoto nipinle Eko iyen Alaaji Musiliu Akinsanya iyen M.c Oluomo se febun oko ayokele SUV t'ore fun un.


No comments:

Post a Comment

Pages