Biola Eyin oka n bebe fun iranlowo owo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Thursday, August 11, 2022

Biola Eyin oka n bebe fun iranlowo owo

Nitori purodusa e iyen Ogbeni Ademola Adelakun ni arewa obinrin onitiata nni iyen Biola Eyin oka se n sunkun lori ero ayelujara to si n be awon ololufe re lati ran purodusa e iyen okunrin to koko sawari e nidi ise tiata Ogbeni Ademola Adelakun to ni ipenija ti won si ti ge ese re kan sugbon to si nilo owo to le ni milioonu meji lati lo fi sise Abe Lorile ede Germany.
Ogun milioonu lowo ti won niilo , sugbon ti won ti ri millioonu mejila.E le fowo ranse si Ogbeni Ademola pelu Akanti nomba yii ,0431383423 Adelakun Olubukola Olufisayo gtbank.


No comments:

Post a Comment

Pages