Oloogbe Ajileye dena mi lati lo si Meka--Abija - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo


Workers delight

Friday, August 12, 2022

Oloogbe Ajileye dena mi lati lo si Meka--Abija

Alaaji Tajudeen Oyewole iyen Abija wara bii ekun ti so pe idi ti oga oun iyen oloogbe Ajileye fi Dena Lili si Meka oun lodun die seyin ni enikeni ko le so sugbon ti oun dupe pe leyin odun meedogun oun papa di Alaaji
Bee lo tun n dupe lowo Olorun ti ko se Meka ni eewo fun oun.


No comments:

Post a Comment

Pages