Loooto lo paro pe ise isegun loun se fomo odun metala naa sugbon asiri ti pada tu pe nise ni Wolii Akingbaso Adeleye fipa ba omo naa sun.Agbenuso olopaa ipinle Ekiti iyen Abutu Sunday fidi isele naa mule to si so pe ki Ogbeni yii lo gbategun die logba ewon kan nipinle Ekiti
No comments:
Post a Comment